Jẹnẹsisi 8:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó tún dúró fún ọjọ́ meje sí i, lẹ́yìn náà, ó tún rán àdàbà náà jáde, ṣugbọn àdàbà náà kò pada sọ́dọ̀ Noa mọ́.

Jẹnẹsisi 8

Jẹnẹsisi 8:5-18