Jẹnẹsisi 7:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo ẹran ati àwọn tí wọ́n mọ́ ati àwọn tí wọn kò mọ́, àwọn ẹyẹ ati gbogbo ohun tí ń fàyà fà lórí ilẹ̀,

Jẹnẹsisi 7

Jẹnẹsisi 7:7-14