Jẹnẹsisi 7:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé ọjọ́ meje ló kù tí n óo bẹ̀rẹ̀ sí rọ òjò sórí ilẹ̀ fún ogoji ọjọ́ tọ̀sán-tòru, gbogbo ẹ̀dá alààyè tí mo dá ni yóo sì parun lórí ilẹ̀ ayé.”

Jẹnẹsisi 7

Jẹnẹsisi 7:1-10