Jẹnẹsisi 6:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìtàn ìran Noa nìyí: Noa jẹ́ olódodo, òun nìkan ṣoṣo ni eniyan pípé ní àkókò tirẹ̀, ó sì wà ní ìrẹ́pọ̀ pẹlu OLUWA.

Jẹnẹsisi 6

Jẹnẹsisi 6:6-18