Jẹnẹsisi 6:2 BIBELI MIMỌ (BM)

nígbà náà ni àwọn ẹ̀dá ọ̀run lọkunrin ṣe akiyesi pé àwọn ọmọbinrin tí eniyan ń bí lẹ́wà gidigidi, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí fẹ́ èyí tí ó wù wọ́n lára wọn.

Jẹnẹsisi 6

Jẹnẹsisi 6:1-11