Jẹnẹsisi 50:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní tiyín, ẹ gbèrò ibi sí mi, ṣugbọn Ọlọrun yí i pada sí rere, kí ó lè dá ẹ̀mí ọpọlọpọ eniyan tí wọ́n wà láàyè lónìí sí.

Jẹnẹsisi 50

Jẹnẹsisi 50:12-24