Jẹnẹsisi 50:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn arakunrin rẹ̀ náà sì wá, wọ́n wólẹ̀ níwájú rẹ̀, wọ́n ní, “Wò ó, a di ẹrú rẹ.”

Jẹnẹsisi 50

Jẹnẹsisi 50:8-26