Jẹnẹsisi 50:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn arakunrin Josẹfu rí i pé baba àwọn ti kú, wọ́n ní, “Ó ṣeéṣe kí Josẹfu kórìíra wa, kí ó sì gbẹ̀san gbogbo ibi tí a ti ṣe sí i.”

Jẹnẹsisi 50

Jẹnẹsisi 50:13-20