Jẹnẹsisi 50:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n dé ibi ìpakà Atadi, níwájú Jọdani, wọ́n pohùnréré ẹkún, Josẹfu sì ṣọ̀fọ̀ baba rẹ̀ fún ọjọ́ meje.

Jẹnẹsisi 50

Jẹnẹsisi 50:1-12