Jẹnẹsisi 5:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo ọdún tí Lamẹki gbé láyé jẹ́ ẹẹdẹgbẹrin ọdún ó lé mẹtadinlọgọrin (777) kí ó tó kú.

Jẹnẹsisi 5

Jẹnẹsisi 5:28-32