Jẹnẹsisi 5:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Enọku wà ní ìrẹ́pọ̀ pẹlu Ọlọrun, nígbà tí ó yá, wọn kò rí i mọ́ nítorí pé Ọlọrun mú un lọ.

Jẹnẹsisi 5

Jẹnẹsisi 5:21-28