Jẹnẹsisi 5:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn tí ó bí Metusela, ó wà ní ìrẹ́pọ̀ pẹlu Ọlọrun fún ọọdunrun (300) ọdún, ó sì bí àwọn ọmọ mìíràn lọkunrin ati lobinrin.

Jẹnẹsisi 5

Jẹnẹsisi 5:12-27