Jẹnẹsisi 5:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn tí ó bí Kenani, ó gbé ẹgbẹrin ọdún ó lé mẹẹdogun (815) láyé, ó sì bí àwọn ọmọ mìíràn lọkunrin ati lobinrin.

Jẹnẹsisi 5

Jẹnẹsisi 5:3-18