Jẹnẹsisi 49:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Juda, àwọn arakunrin rẹ yóo máa yìn ọ́,apá rẹ yóo sì ká àwọn ọ̀tá rẹ;àwọn ọmọ baba rẹ yóo máa tẹríba fún ọ.

Jẹnẹsisi 49

Jẹnẹsisi 49:3-17