Jẹnẹsisi 49:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Jakọbu ranṣẹ pe àwọn ọmọ rẹ̀, ó wí fún wọn pé, “Ẹ kó ara yín jọ kí n lè sọ ohun tí yóo ṣẹlẹ̀ si yín ní ọjọ́ iwájú fún yín.

Jẹnẹsisi 49

Jẹnẹsisi 49:1-4