Jẹnẹsisi 48:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó fi ọwọ́ ọ̀tún mú Efuraimu, ó fà á súnmọ́ ẹ̀gbẹ́ ọwọ́ òsì baba rẹ̀, ó fi ọwọ́ òsì mú Manase, ó fà á súnmọ́ ẹ̀gbẹ́ ọwọ́ ọ̀tún baba rẹ̀.

Jẹnẹsisi 48

Jẹnẹsisi 48:10-14