Jẹnẹsisi 47:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Josẹfu bá mú Jakọbu baba rẹ̀ wọlé láti fihan Farao, Jakọbu sì súre fún Farao.

Jẹnẹsisi 47

Jẹnẹsisi 47:3-10