Jẹnẹsisi 47:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọdún mẹtadinlogun ni Jakọbu gbé sí i ní ilẹ̀ Ijipti, gbogbo ọdún tí ó gbé láyé sì jẹ́ ọdún mẹtadinlaadọjọ (147).

Jẹnẹsisi 47

Jẹnẹsisi 47:20-31