Jẹnẹsisi 47:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n dáhùn pé, “Ìwọ ni o gbà wá lọ́wọ́ ikú, bí ó bá ti wù ọ́ bẹ́ẹ̀, a óo di ẹrú Farao.”

Jẹnẹsisi 47

Jẹnẹsisi 47:24-29