Jẹnẹsisi 47:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Josẹfu sọ fún àwọn eniyan náà pé, “Àtẹ̀yin, àtilẹ̀ yín, láti òní lọ, mo ra gbogbo yín fún Farao. Irúgbìn nìyí, ẹ lọ gbìn ín sinu oko yín.

Jẹnẹsisi 47

Jẹnẹsisi 47:16-31