Jẹnẹsisi 47:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Josẹfu bá dá wọn lóhùn pé, “Bí kò bá sí owó lọ́wọ́ yín mọ́, ẹ kó àwọn ẹran ọ̀sìn yín wá, n óo sì fun yín ní oúnjẹ dípò wọn.”

Jẹnẹsisi 47

Jẹnẹsisi 47:14-26