Jẹnẹsisi 47:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo owó tí àwọn ará ilẹ̀ Ijipti ati àwọn ará ilẹ̀ Kenaani ní patapata ni wọ́n kó tọ Josẹfu wá láti fi ra oúnjẹ. Josẹfu sì kó gbogbo owó náà lọ fún Farao.

Jẹnẹsisi 47

Jẹnẹsisi 47:12-22