Jẹnẹsisi 46:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Josẹfu sọ fún àwọn arakunrin rẹ̀ ati gbogbo ìdílé baba rẹ̀ pé òun óo lọ sọ fún Farao pé àwọn arakunrin òun ati ìdílé baba òun tí wọ́n wà ní ilẹ̀ Kenaani ti dé sọ́dọ̀ òun.

Jẹnẹsisi 46

Jẹnẹsisi 46:30-34