Jẹnẹsisi 46:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun wí pé, “Èmi ni Ọlọrun baba rẹ, má fòyà rárá láti lọ sí Ijipti, nítorí pé n óo sọ ọ́ di orílẹ̀-èdè ńlá níbẹ̀.

Jẹnẹsisi 46

Jẹnẹsisi 46:1-4