Jẹnẹsisi 46:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Asenati, ọmọbinrin Pọtifera bí Manase ati Efuraimu fún Josẹfu ní ilẹ̀ Ijipti. Pọtifera ni babalóòṣà oriṣa Oni, ní Ijipti.

Jẹnẹsisi 46

Jẹnẹsisi 46:10-28