Jẹnẹsisi 46:15 BIBELI MIMỌ (BM)

(Àwọn ni ọmọ tí Lea bí fún Jakọbu ní Padani-aramu ati Dina, ọmọ rẹ̀ obinrin.) Gbogbo àwọn ọmọ rẹ̀ lọkunrin ati lobinrin jẹ́ mẹtalelọgbọn.

Jẹnẹsisi 46

Jẹnẹsisi 46:6-20