Jẹnẹsisi 46:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ ti Juda ni: Eri, Onani, Ṣela, Peresi, ati Sera, (ṣugbọn, Eri ati Onani ti kú ní ilẹ̀ Kenaani) àwọn ọmọ ti Peresi ni Hesironi ati Hamuli.

Jẹnẹsisi 46

Jẹnẹsisi 46:11-15