Jẹnẹsisi 45:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n sọ fún un pé, “Josẹfu kò kú, ó wà láàyè, ati pé òun ni alákòóso gbogbo ilẹ̀ Ijipti.” Nígbà tí ó gbọ́ bẹ́ẹ̀, orí rẹ̀ fò lọ fee, kò kọ́ gbà wọ́n gbọ́.

Jẹnẹsisi 45

Jẹnẹsisi 45:24-28