Jẹnẹsisi 45:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá ní kí àwọn arakunrin òun máa lọ, bí wọ́n sì ti fẹ́ máa lọ, ó kìlọ̀ fún wọn pé kí wọ́n má bá ara wọn jà lọ́nà.

Jẹnẹsisi 45

Jẹnẹsisi 45:19-28