Jẹnẹsisi 45:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó fún olukuluku wọn ní ìpààrọ̀ aṣọ kọ̀ọ̀kan, ṣugbọn ó fún Bẹnjamini ní ọọdunrun (300) ṣekeli fadaka ati ìpààrọ̀ aṣọ marun-un.

Jẹnẹsisi 45

Jẹnẹsisi 45:16-28