Jẹnẹsisi 45:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bú sẹ́kún, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí pohùnréré ẹkún tóbẹ́ẹ̀ tí àwọn ará Ijipti ati gbogbo ilé Farao gbọ́ ẹkún rẹ̀.

Jẹnẹsisi 45

Jẹnẹsisi 45:1-7