Jẹnẹsisi 45:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ sọ fún un pé mo sọ pé kí ó wá máa gbé ní ilẹ̀ Goṣeni nítòsí mi, òun ati àwọn ọmọ rẹ̀, ati àwọn ọmọ ọmọ rẹ̀, ati agbo mààlúù rẹ̀, ati ohun gbogbo tí ó ní.

Jẹnẹsisi 45

Jẹnẹsisi 45:1-20