Jẹnẹsisi 44:23-25 BIBELI MIMỌ (BM)

23. O bá sọ fún àwa iranṣẹ rẹ pé bí àbíkẹ́yìn wa patapata kò bá bá wa wá, a kò ní rí ojú rẹ nílẹ̀ mọ́.

24. “Nígbà tí a pada dé ọ̀dọ̀ baba wa, iranṣẹ rẹ, a rò fún un bí o ti wí.

25. Nígbà tí ó ní kí á tún lọ ra oúnjẹ díẹ̀ wá,

Jẹnẹsisi 44