Jẹnẹsisi 44:22 BIBELI MIMỌ (BM)

A sì sọ fún ọ pé, ‘Ọmọ náà kò lè fi baba rẹ̀ sílẹ̀, nítorí pé bí ó bá fi baba rẹ̀ sílẹ̀, baba rẹ̀ yóo kú.’

Jẹnẹsisi 44

Jẹnẹsisi 44:17-25