Jẹnẹsisi 44:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Juda ati àwọn arakunrin rẹ̀ pada dé ilé Josẹfu, ó ṣì wà nílé, wọ́n bá dọ̀bálẹ̀ gbalaja níwájú rẹ̀.

Jẹnẹsisi 44

Jẹnẹsisi 44:12-15