Jẹnẹsisi 44:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Iranṣẹ náà bá bẹ̀rẹ̀ sí wo àpò wọn, ó bẹ̀rẹ̀ lórí àpò èyí àgbà patapata, títí dé orí ti àbíkẹ́yìn wọn, wọ́n bá ife náà ninu ẹrù Bẹnjamini.

Jẹnẹsisi 44

Jẹnẹsisi 44:10-18