Jẹnẹsisi 43:5 BIBELI MIMỌ (BM)

ṣugbọn bí o kò bá jẹ́ kí ó bá wa lọ, a kò ní lọ, nítorí pé ọkunrin náà tẹnumọ́ ọn fún wa pé a kò ní fi ojú kan òun láìjẹ́ pé arakunrin wa bá wa wá.”

Jẹnẹsisi 43

Jẹnẹsisi 43:1-12