Jẹnẹsisi 43:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Ojú tí ó gbé sókè, ó rí Bẹnjamini ọmọ ìyá rẹ̀, ó bá bèèrè pé, “Ṣé arakunrin yín tí í ṣe àbíkẹ́yìn tí ẹ wí nìyí? Kí Ọlọrun fi ojurere wò ọ́, ọmọ mi.”

Jẹnẹsisi 43

Jẹnẹsisi 43:23-34