Jẹnẹsisi 43:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí Ọlọrun Olodumare jẹ́ kí ọkunrin náà ṣàánú yín, kí ó sì dá arakunrin yín kan yòókù ati Bẹnjamini pada. Bí mo bá tilẹ̀ wá ṣòfò àwọn ọmọ mi nígbà náà, n óo gbà pé mo ṣòfò wọn.”

Jẹnẹsisi 43

Jẹnẹsisi 43:9-22