Jẹnẹsisi 42:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé Josẹfu mọ̀ dájú pé àwọn arakunrin òun ni wọ́n, wọn kò mọ̀ ọ́n.

Jẹnẹsisi 42

Jẹnẹsisi 42:1-15