Jẹnẹsisi 42:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Jakọbu kò jẹ́ kí Bẹnjamini, arakunrin Josẹfu bá àwọn arakunrin rẹ̀ lọ, nítorí ẹ̀rù ń bà á kí nǹkankan má tún lọ ṣẹlẹ̀ sí òun náà.

Jẹnẹsisi 42

Jẹnẹsisi 42:1-5