Jẹnẹsisi 42:37 BIBELI MIMỌ (BM)

Reubẹni bá wí fún baba rẹ̀ pé, “Pa àwọn ọmọ mi mejeeji, bí n kò bá mú Bẹnjamini pada wá fún ọ. Fi lé mi lọ́wọ́, n óo sì mú un pada wá fún ọ.”

Jẹnẹsisi 42

Jẹnẹsisi 42:30-38