Jẹnẹsisi 42:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn kò mọ̀ pé Josẹfu gbọ́ gbogbo ohun tí wọn ń wí, nítorí pé ògbufọ̀ ni wọ́n fi ń bá ara wọn sọ̀rọ̀.

Jẹnẹsisi 42

Jẹnẹsisi 42:22-26