Jẹnẹsisi 42:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó di ọjọ́ kẹta, Josẹfu wí fún wọn pé, “Mo bẹ̀rù Ọlọrun, nítorí náà, bí ẹ bá ṣe ohun tí n óo sọ fun yín yìí, n óo dá ẹ̀mí yín sí.

Jẹnẹsisi 42

Jẹnẹsisi 42:8-25