Jẹnẹsisi 42:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ohun tí n óo fi mọ̀ pé olóòótọ́ ni yín nìyí: mo fi orúkọ Farao búra, ẹ kò ní jáde níhìn-ín àfi bí ẹ bá mú àbíkẹ́yìn baba yín wá.

Jẹnẹsisi 42

Jẹnẹsisi 42:10-24