Jẹnẹsisi 41:56 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ìyàn náà tàn káàkiri gbogbo ilẹ̀, Josẹfu ṣí àwọn àká tí wọ́n kó oúnjẹ pamọ́ sí, ó ń ta oúnjẹ fún àwọn ará Ijipti, nítorí ìyàn náà mú gidigidi ní ilẹ̀ náà.

Jẹnẹsisi 41

Jẹnẹsisi 41:48-57