Jẹnẹsisi 41:54 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọdún meje ìyàn sì bẹ̀rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Josẹfu ti wí, ìyàn mú ní ilẹ̀ gbogbo, ṣugbọn oúnjẹ wà ní gbogbo ilẹ̀ Ijipti.

Jẹnẹsisi 41

Jẹnẹsisi 41:48-57