Jẹnẹsisi 41:51 BIBELI MIMỌ (BM)

Josẹfu sọ ọmọ rẹ̀ kinni ní Manase, ó ní, “Ọlọ́run ti mú mi gbàgbé gbogbo ìnira mi ati ilé baba mi.”

Jẹnẹsisi 41

Jẹnẹsisi 41:43-55