Jẹnẹsisi 41:46 BIBELI MIMỌ (BM)

Josẹfu jẹ́ ọmọ ọgbọ̀n ọdún nígbà tí ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ lábẹ́ Farao, ọba Ijipti. A máa lọ láti ààfin ọba Farao káàkiri gbogbo ilẹ̀ Ijipti.

Jẹnẹsisi 41

Jẹnẹsisi 41:38-49