Jẹnẹsisi 41:44 BIBELI MIMỌ (BM)

Farao tún sọ fún un pé, “Èmi ni Farao, ẹnikẹ́ni kò gbọdọ̀ ṣe ohunkohun ní ilẹ̀ Ijipti láìjẹ́ pé o fọwọ́ sí i.”

Jẹnẹsisi 41

Jẹnẹsisi 41:37-51